Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 4:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èsu sì mú un lọ sí Jerúsálémù, ó sì gbé e lé ṣóńṣo tẹ́ḿpílì, ó sì wí fún un pé, “Bí ìwọ bá ṣe Ọmọ Ọlọ́run, bẹ́ sílẹ̀ fún ara rẹ láti ibí yìí:

Ka pipe ipin Lúùkù 4

Wo Lúùkù 4:9 ni o tọ