Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 4:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ẹ̀mí èṣù sì jáde lára ẹni púpọ̀ pẹ̀lú, wọ́n ń kígbe, wí pé, “Ìwọ ni Ọmọ Ọlọ́run!” Ó sì ń bá wọn wí kò sì jẹ́ kí wọn kí ó fọhùn: nítorí tí wọ́n mọ̀ pé òun ni Kírísítì náà.

Ka pipe ipin Lúùkù 4

Wo Lúùkù 4:41 ni o tọ