Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 3:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jòhánù dáhùn ó sì wí fún gbogbo wọn pé, “Lóòótọ́ ni èmi ń fi omi bamtíìsì yín; ṣùgbọ́n ẹni tí ó lágbára jù mí lọ ńbọ̀, okùn bàtà ẹ̀ṣẹ̀ ẹni tí èmi kò tó ítú: òun ni yóò fi Ẹ̀mí Mímọ́ àti iná bamtísì yín:

Ka pipe ipin Lúùkù 3

Wo Lúùkù 3:16 ni o tọ