Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 22:66 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ilẹ̀ sì mọ́, ìjọ àwọn alàgbà àwọn ènìyàn péjọ pọ̀, àti àwọn olórí àlùfáà, àti àwọn akọ̀wé, wọ́n sì fà á lọ sí àjọ wọn, wọ́n ń wí pé,

Ka pipe ipin Lúùkù 22

Wo Lúùkù 22:66 ni o tọ