Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 22:49 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí àwọn tí ó wà lọ́dọ̀ rẹ̀ ń wo bí nǹkan yóò ti jásí, wọ́n bi í pé, “Olúwa kí àwá fi idà ṣá wọn?”

Ka pipe ipin Lúùkù 22

Wo Lúùkù 22:49 ni o tọ