Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 22:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí mo wí fún yín pé, ‘Èyí tí a ti kọ̀wé rẹ̀ kò lè ṣe kí ó má ṣẹ lára mi, A sì kà á mọ́ àwọn arúfin.’ Nítorí àwọn ohun wọ̀nyí nípa ti èmi yóò ní ìmúṣẹ.”

Ka pipe ipin Lúùkù 22

Wo Lúùkù 22:37 ni o tọ