Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 22:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wí fún wọn pé, “Nígbà tí mo rán yín lọ láìní àpò-owó, àti àpò, àti bàtà, ọ̀dá ohun kan dá yín bí?”Wọ́n sì wí pé, “Rárá!”

Ka pipe ipin Lúùkù 22

Wo Lúùkù 22:35 ni o tọ