Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 22:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí ẹ sì wí fún baálé ilé náà pé, ‘Olùkọ́ wí fún ọ pé: Níbo ni gbọ̀ngàn àpèjẹ náà gbé wà, níbi tí èmi ó gbé jẹ ìrékọjá pẹ̀lú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn mi?’

Ka pipe ipin Lúùkù 22

Wo Lúùkù 22:11 ni o tọ