Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 21:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn ó sì ti ojú idà ṣubú, a ó sì dì wọ́n ní ìgbékùn lọ sí orílẹ̀-èdè gbogbo; Jerúsálémù yóò sì di ìtẹ̀mọ́lẹ̀ lẹ́sẹ̀ àwọn aláìkọlà, títí àkókò àwọn aláìkọlà yóò fi kún.

Ka pipe ipin Lúùkù 21

Wo Lúùkù 21:24 ni o tọ