Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 2:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì bí àkọ́bí rẹ̀ ọmọkùnrin, ó sì fi ọ̀já wé e, ó sì tẹ́ ẹ sínú ibùjẹ ẹran; nítorí tí àyè kò sí fún wọn nínú ilé èrò.

Ka pipe ipin Lúùkù 2

Wo Lúùkù 2:7 ni o tọ