Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 2:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Síméónì sì súre fún wọn, ó sì wí fún Màríà ìyá rẹ̀ pé: “Kíyèsí i, a gbé ọmọ yìí kalẹ̀ fún ìṣubú àti ìdìde ọ̀pọ̀ ènìyàn ní Ísírẹ́lì; àti fún àmì tí a ń sọ̀rọ̀ òdì sí;

Ka pipe ipin Lúùkù 2

Wo Lúùkù 2:34 ni o tọ