Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 2:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ti ipa Ẹ̀mí wá sínú tẹ́ḿpìlì: nígbà tí àwọn òbí rẹ̀ sì gbé ọmọ náà Jésù wá, láti ṣe fún un bí ìṣe òfin,

Ka pipe ipin Lúùkù 2

Wo Lúùkù 2:27 ni o tọ