Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 2:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sì kíyèsí i, ọkùnrin kan wà ní Jerúsálémù, orúkọ rẹ̀ a máa jẹ́ Ṣíméónì; ọkùnrin náà sì ṣe olóòótọ́ àti olùfọkànsìn, ó ń retí ìtùnú Ísírẹ́lì: Ẹ̀mí mímọ́ sì bà lé e.

Ka pipe ipin Lúùkù 2

Wo Lúùkù 2:25 ni o tọ