Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 2:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ọjọ́ ìwẹ̀nù Màríà sì pé gẹ́gẹ́ bí òfin Mósè, Josefu àti Màríà gbé Jésù wá sí Jerúsálémù láti fi í fún Olúwa;

Ka pipe ipin Lúùkù 2

Wo Lúùkù 2:22 ni o tọ