Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 19:47-48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

47. Ó sì ń kọ́ni lójoojúmọ́ ní tẹ́ḿpìlì, Ṣùgbọ́n àwọn olórí àlùfáà, àti àwọn akọ̀wé, àti àwọn olórí àwọn ènìyàn ń wá ọ̀nà láti pa á run.

48. Wọn kò sì rí nǹkan kan tí wọn ìbá ṣe; nítorí gbogbo ènìyàn ṣù mọ́ ọn láti gbọ́rọ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Lúùkù 19