Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 19:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó sì ti súnmọ́ etí ibẹ̀ ní gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ òkè olófì, gbogbo àwọn ọmọ-ẹ̀yìn bẹ̀rẹ̀ sí í yọ̀, wọ́n sì fi ohùn rara yin Ọlọ́run, nítorí iṣẹ́ ńlá gbogbo tí wọ́n ti rí;

Ka pipe ipin Lúùkù 19

Wo Lúùkù 19:37 ni o tọ