Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 19:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí wọ́n sì ti ń tú ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà, àwọn Olúwa rẹ̀ bi wọ́n pé, “Èéṣe tí ẹ̀yin fi ń tu kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà?”

Ka pipe ipin Lúùkù 19

Wo Lúùkù 19:33 ni o tọ