Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 19:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Olúwa rẹ̀ sì wí fún un pé, ‘O ṣeun, ìwọ ọmọ-ọ̀dọ̀ rere! Nítorí tí ìwọ ṣe olóòótọ́ ní ohun kínkínní, gba àṣẹ lórí ìlú mẹ́wàá.’

Ka pipe ipin Lúùkù 19

Wo Lúùkù 19:17 ni o tọ