Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 17:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí kì yóò kúkú wí fún un pé, ‘Pèsè ohun tí èmi yóò jẹ, sì di àmùrè, kí ìwọ kí ó máa ṣe ìránṣẹ́ fún mi, títí èmi ó fi jẹ kí èmi ó sì mu tán; lẹ́yìn náà ni ìwọ ó sì jẹ, tí ìwọ ó sì mu’?

Ka pipe ipin Lúùkù 17

Wo Lúùkù 17:8 ni o tọ