Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 16:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nígbà náà ni ó sì bi ẹnìkejì pé, ‘Èló ni ìwọ́ jẹ?’“Òun sì wí pé, ‘Ọgọ́rùnún òsùwọ̀n àlìkámà.’“Ó sì wí fún un pé, ‘Mú ìwé rẹ, kí o sì kọ ọgọ́rin.’

Ka pipe ipin Lúùkù 16

Wo Lúùkù 16:7 ni o tọ