Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 16:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kò sí ìránṣẹ́ kan tí ó le sin olúwa méjì: àyàfi kí ó kórìíra ọ̀kan, yóò sì fẹ́ èkejì; tàbí yóò fi ara mọ́ ọ̀kan yóò sì yan èkejì ní ìpọ̀sì. Ẹ̀yin kò lè sin Ọlọ́run pẹ̀lú mámónì.”

Ka pipe ipin Lúùkù 16

Wo Lúùkù 16:13 ni o tọ