Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 14:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí ẹnìkan bá tọ̀ mí wá, tí kò sì kóríra bàbá rẹ̀, àti ìyá, àti aya, àti ọmọ, àti arákùnrin, àti arábìnrin, àní àti ọkàn ara rẹ̀ pẹ̀lú, kò lè ṣe ọmọ-ẹ̀yìn mi.

Ka pipe ipin Lúùkù 14

Wo Lúùkù 14:26 ni o tọ