Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 13:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Jerúsálémù, Jerúsálémù, ìwọ tí o pa àwọn wòlíì, tí o sì sọ òkúta lu àwọn tí a rán sí ọ pa; nígbà mélòó ni èmi ń fẹ́ ràgà bo àwọn ọmọ rẹ, bí àgbébọ̀ ti í ràgà bo àwọn ọmọ rẹ̀ lábẹ́ apá rẹ̀, ṣùgbọ́n ẹ̀yin kò fẹ́!

Ka pipe ipin Lúùkù 13

Wo Lúùkù 13:34 ni o tọ