Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 13:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní wákàtí kan náà, díẹ̀ nínú àwọn Farisí tọ̀ ọ́ wá, wọ́n sì wí fún un pé, “Jáde, kí ìwọ sì lọ kúrò níhín-ín yìí: nítorí Hẹ́rọ́dù ń fẹ́ pa ọ́.”

Ka pipe ipin Lúùkù 13

Wo Lúùkù 13:31 ni o tọ