Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 13:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Òun ó sì wí pé, ‘Èmi wí fún yín èmi kò mọ̀ ibi tí ẹ̀yin ti wá; ẹ lọ kúrò lọ́dọ̀ mi gbogbo ẹ̀yin tí ń ṣiṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀.’

Ka pipe ipin Lúùkù 13

Wo Lúùkù 13:27 ni o tọ