Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 13:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olórí sínágọ́gù sì kún fún ìrúnnú, nítorí tí Jésù múni láradá ní ọjọ́ ìsinmi, ó sì wí fún ìjọ ènìyàn pé, Ijọ́ mẹ́fà ní ń bẹ tí a fi í ṣiṣẹ́: nínú wọn ni kí ẹ̀yin kí ó wá kí á ṣe dídá ara yín, kí ó má se ní ọjọ́ ìsinmi.

Ka pipe ipin Lúùkù 13

Wo Lúùkù 13:14 ni o tọ