Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 12:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ẹnikẹ́ni tí ó bá sọ̀rọ̀ òdì sí ọmọ ènìyàn, a ó dárí rẹ̀ jìn-ín; ṣùgbọ́n ẹnikẹ́ni tí ó bá sọ̀rọ̀ òdì sí ẹ̀mí mímọ́, a kì yóò dárí rẹ̀ jìn-ín.

Ka pipe ipin Lúùkù 12

Wo Lúùkù 12:10 ni o tọ