Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 11:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nígbà tí ẹ̀mí àìmọ́ bá jáde kúrò lára ènìyàn, a máa rìn kiri ní ibi gbígbẹ, a máa wá ibi ìsinmi; nígbà tí kò bá sì rí, a wí pé, ‘Èmi yóò padà lọ sí ilé mi ní ibi tí mo gbé ti jáde wá.’

Ka pipe ipin Lúùkù 11

Wo Lúùkù 11:24 ni o tọ