Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 1:66 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì jẹ́ ohun ìyọnu fún gbogbo àwọn tí ó gbọ́ nípa rẹ̀, wọ́n ń wí pé, “Irú ọmọ kínni èyí yóò jẹ́?” Nítirí tí ọwọ́ Olúwa wà pẹ̀lú rẹ̀.

Ka pipe ipin Lúùkù 1

Wo Lúùkù 1:66 ni o tọ