Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 1:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Màríà bèèrè lọ́wọ́ ańgẹ́lì náà pé, “Èyí yóò ha ti ṣe rí bẹ́ẹ̀, nígbà tí èmi kò tii mọ ọkùnrin.”

Ka pipe ipin Lúùkù 1

Wo Lúùkù 1:34 ni o tọ