Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kólósè 3:24-25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

24. Kí ẹ mọ̀ pé lọ́wọ́ Olúwa ni ẹ̀yin ó gba èrè ogun: nítorí ẹ̀yin ń sìn Olúwa Kírísítì.

25. Ṣùgbọ́n ẹnikẹ́ni tí ó bá ṣe àìṣòdodo, yóò gbàá padà nítorí àìṣòdodo náà tí ó ti ṣe: kò sì sí ojúṣáájú.

Ka pipe ipin Kólósè 3