Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kólósè 2:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ máa kiyesii pé ẹnikẹ́ni kò fi ìmọ̀ àti ẹtan asan ko yín ní ìgbèkùn, èyí tí ó jẹmọ́ ìtàn ènìyàn bi ìpilẹ̀sẹ ẹ̀kọ́ ayé láìse ohun tí Kírísítì ti wí.

Ka pipe ipin Kólósè 2

Wo Kólósè 2:8 ni o tọ