Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kólósè 2:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo fẹ́ kí ẹ mọ bí mo ti ń jìjàkadì fún un yín àti fún àwọn ará Laodékíà àti fún ọ̀pọ̀ ènìyàn mìíràn tí wọn kò ì tí ì rí mi sójú rí.

Ka pipe ipin Kólósè 2

Wo Kólósè 2:1 ni o tọ