Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kólósè 1:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti nípaṣẹ̀ rẹ̀ láti bá ohun gbogbo làjà nǹkan tí ń bẹ láyé àti èyí tí ń bẹ lọ́rùn, nípa mímú àlàáfíà wá nípaṣẹ̀ ẹ̀jẹ̀ rẹ̀, tí a ta sílẹ̀ lórí igi àgbélèbùú.

Ka pipe ipin Kólósè 1

Wo Kólósè 1:20 ni o tọ