Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Júdà 1:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti àwọn ańgẹ́lì tí kò tọ́jú ipò ọlá wọn, ṣùgbọ́n tí wọn fi ipò wọn sílẹ̀, àwọn tí ó pamọ́ sínú ẹ̀wọ̀n àìnípẹ̀kun ní ìṣàlẹ̀ òkùnkùn de ìdájọ ọjọ́ ńlá nì.

Ka pipe ipin Júdà 1

Wo Júdà 1:6 ni o tọ