Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 9:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa ní láti ṣe iṣẹ́ ẹni tí ó rán mi, níwọ̀n ìgbà tí ó ba ti jẹ́ ọ̀sán: òru ń bọ̀ wá nígbà tí ẹnìkan kì yóò lè ṣe iṣẹ́.

Ka pipe ipin Jòhánù 9

Wo Jòhánù 9:4 ni o tọ