Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 9:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn Ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ sì bi í léèrè, pé, “Olùkọ́, ta ní ó dẹ́ṣẹ̀, ọkùnrin yìí tàbí àwọn òbí rẹ̀, tí a fi bí i ní afọ́jú?”

Ka pipe ipin Jòhánù 9

Wo Jòhánù 9:2 ni o tọ