Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 8:57-59 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

57. Nítorí náà, àwọn Júù wí fún un pé, “Ọdún rẹ kò ì tó àádọ́ta, ìwọ sì ti rí Ábúráhámù?”

58. Jésù sì wí fún wọn pé, “Lóòótọ́ lóòótọ́ ni mo wí fún yín, kí Ábúráhámù tó wà, èmi nìyìí.”

59. Nítorí náà wọ́n gbé òkúta láti sọ lù ú: ṣùgbọ́n Jésù fi ara rẹ̀ pamọ́, ó sì jáde kúrò ní tẹ́ḿpílì.

Ka pipe ipin Jòhánù 8