Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 8:54 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù dáhùn wí pé, “Bí mo bá yin ara mi lógo, ògo mi kò jẹ́ ǹkan; Baba mi ni ẹni tí ń yìn mí lógo, ẹni tí ẹ̀yin wí pé, Ọlọ́run yín ní i ṣe:

Ka pipe ipin Jòhánù 8

Wo Jòhánù 8:54 ni o tọ