Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 8:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo mọ̀ pé irú-ọmọ Ábúráhámù ni ẹ̀yin jẹ́; ṣùgbọ́n ẹ ń wá ọ̀nà láti pa mí nítorí ọ̀rọ̀ mi kò rí àyè nínú yín. Jésù sọ ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa ara rẹ̀

Ka pipe ipin Jòhánù 8

Wo Jòhánù 8:37 ni o tọ