Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 8:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn akọ̀wé àti àwọn Farisí sì mú obìnrin kan wá sọ́dọ̀ rẹ̀, tí a mú ní ṣíṣe panṣágà; wọ́n sì mú un dúró láàrin.

Ka pipe ipin Jòhánù 8

Wo Jòhánù 8:3 ni o tọ