Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 8:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo ní ohun púpọ̀ láti sọ, àti láti ṣe ìdájọ́ nípa yín: ṣùgbọ́n olóòótọ́ ni ẹni tí ó rán mi, ohun tí èmi sì ti gbọ́ láti ọ̀dọ̀ rẹ̀ wá, wọ̀nyí ni èmi ń sọ fún aráyé.”

Ka pipe ipin Jòhánù 8

Wo Jòhánù 8:26 ni o tọ