Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 8:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀rọ̀ wọ̀nyí ni Jésù sọ níbi ìṣúra, bí ó ti ń kọ́ni ní tẹ́ḿpìlì: ẹnikẹ́ni kò sì mú un; nítorí wákàtí rẹ̀ kò tíì dé.

Ka pipe ipin Jòhánù 8

Wo Jòhánù 8:20 ni o tọ