Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 7:46-49 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

46. Àwọn ẹ̀ṣọ́ dáhùn wí pé, “Kò sí ẹni tí ó tí ì sọ̀rọ̀ bí ọkùnrin yìí rí!”

47. Nítorí náà àwọn Farisí dá wọn lóhùn pé, “A ha tan ẹ̀yin jẹ pẹ̀lú bí?

48. Ǹjẹ́ nínú àwọn ìjòyè, tàbí àwọn Farisí ti gbà á gbọ́ bí?

49. Ṣùgbọ́n ìjọ ènìyàn yìí, tí ko mọ òfin di ẹni ìfibú.”

Ka pipe ipin Jòhánù 7