Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 7:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lọ́jọ́ tó kẹ́yìn, tí í ṣe ọjọ́ ńlá àjọ, Jésù dúró, ó sì kígbe wí pé, “Bí òrùgbẹ bá ń gbẹ ẹnikẹ́ni, kí ó tọ̀ mí wá, kí ó sì mu.

Ka pipe ipin Jòhánù 7

Wo Jòhánù 7:37 ni o tọ