Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 7:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà Jésù wí fún wọn pé, “Níwọ̀n ìgbà díẹ̀ ni èmi yóò wà pẹ̀lú yín, èmi yóò lọ sí ọ̀dọ̀ ẹni tí ó rán mi.

Ka pipe ipin Jòhánù 7

Wo Jòhánù 7:33 ni o tọ