Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 6:65 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wí pé, “Nítorí náà ni mo ṣe wí fún yín pé, kò sí ẹni tí ó lè tọ̀ mí wá, bí kò ṣe pé a fi fún un láti ọ̀dọ̀ Baba mi wá.”

Ka pipe ipin Jòhánù 6

Wo Jòhánù 6:65 ni o tọ