Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 6:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì mú ìṣù àkàrà náà. Nígbà tí ó sì ti dúpẹ́, ó pín wọn fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sì pín wọn fún àwọn tí ó jókòó; bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ sì ni ẹja ní ìwọn bí wọ́n ti ń fẹ́.

Ka pipe ipin Jòhánù 6

Wo Jòhánù 6:11 ni o tọ