Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 5:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ẹ̀gbẹ́ odò yìí ni ọ̀pọ̀ àwọn abirùn ènìyàn máa ń gbé dúbúlẹ̀ sí, àwọn afọ́jú, arọ àti alárùn ẹ̀gbà, wọ́n sì ń dúró de rírú omi.

Ka pipe ipin Jòhánù 5

Wo Jòhánù 5:3 ni o tọ