Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 5:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn náà, Jésù rí i ní tẹ́ḿpìlì ó sì wí fún un pé, “Wò ó, a mú ọ láradá: má se dẹ́sẹ̀ mọ́, kí ohun tí ó burú ju èyí lọ má ba à bá ọ!”

Ka pipe ipin Jòhánù 5

Wo Jòhánù 5:14 ni o tọ